JONILAR

JONILAR

Video/Audio/Lyrics: Infinity – Aye Ole

by | Oct 19, 2016 | Africa

Country: Nigeria

Song: Aye Ole by Infinity

Lyrics

Omo eniyan f’eti si
oro agba, bi o she l’owuro
A she lowo ale

Verse 1
Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d’opin
Aimola eda lo mu eda saniyan ra
Olorun ti seleri, oro baba ko ni ye
Aini gbaggbao lo mu eda raropin
Bi okun n fo, Ti osa n sa, otito wa laaye
Igbabo ni orisun ohun gbogbo

[Chorus]
Ouh, Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [x4 ]

Verse 2
Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F’oju re womi ore k’Oluwa le foju re wo
Abiku ti d’abiye ninu aye mi
[Repeat]

[Chorus]

Bridge
Aye re ko ma ni le
Aye to ba ba Olorun rin, o sho ri re
[Repeat]

Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d’opin

 


DOWNLOAD

Watch the video below

Playlists